INTRODUCTION:
Mo dáńtọ́ nínú kíkọ èdè Yorùbá, gẹ́gẹ́ bíi èdè olóhùn tí a mọ̀n ọ́n sí, àti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ni ó máa ń dára fún ìkọ́ni yìí, ìlànà tí a máa ń tẹ̀lẹ́, Àṣà, Gírámà, Lítíréṣọ̀ kò níí gbẹ́yìn. Akọ́mọlédè; tiwa làṣà ọmọlúàbí. Ìkọ́ni lóríi bí a ṣe ń kọ́ni pẹ̀lú èdè abínibí tó dáńgíjíá, lílo àṣàyàn àwọn ìlànà tó múná dóko.
Ẹ ṣeun.
SUBJECTS:
Yorùbá
LEVELS HANDLED:
Primary School, Junior Secondary School, Senior Secondary School, BSc/ND/NCE/First Degree, Beginner (for languages), Intermediate (for languages)
————
TUTOR, HIRE TEACHERS IN NIGERIA, TEACHERS IN AFRICA, TUTORS, TUTORING, online subject tutor, teacher #tutor #teaching #teach #home #lesson #subject, tutor/classes, Nigerian, African, online tutor, lesson teacher, native teacher, 1-on-1 tutor, private tutor, language tutor, tutor for kids, tutor for adults, Nigerians in diaspora, Tutoring Services